Faith Classics

                          CONFESSION FOR THE MONTH OF MAY, 2016

 

“And the LORD said, I have surely seen the affliction of my people which are in Egypt, and have heard their cry by reason of their taskmasters; for I know their sorrows.” Ex. 3:7

 • I confess Jehovah, the God that answers prayers as my God.
 • I confess Jesus, the way, the truth and the life as my Lord and Saviour.
 • This month and every day of my life the LORD will hear my cry.
 • I am delivered from every taskmaster in the name of Jesus Christ.
 • Afflictions shall be far from me and terror removed away from my tent.
 • In this month of May I shall not labour in vain.

 

IJEWO FUN OSU KARUN ODUN 2016

“Oluwa si wi pe, Nitooto emi ti ri iponju awon eniyan mi ti o wa ni Egipti, mo si gbo igbe won nitori awon akonisise won; nitori ti mo mo ibanuje won.” Ex. 3:7

 

 • Mo jewo Jehovah, Olorun to dahun adura ni Olorun mi
 • Mo jewo Jesu, Oba, Otito ati Iye ni Oluwa ati Olugbala mi.
 • Osu yi ati ojo aye mi Oluwa yio gbo igbe mi.
 • A gba mi sile lowo awon akonisise mi ni Oruko Jesu Kristi
 • Inira yio jina si mi ikolu ni a o mu kuro ni ago mi.
 • Ninu osu karun yi ng ko ji sise lasan.
 • Mo di alabukun fun. Mo ri oju rere gba.     Amin ati Amin.  Aleluya.